Pedantic Educational Consults
FACULTY OF EDUCATION,
DEPARTMENT OF SCIENCE AND TECHNOLOGY EDUCATIONA,
EDUCATIONAL TECHNOLOGY UNIT,
LAGOS STATE UNIVERSITY, OJO LAGOS
Ọ̀sẹ̀ – Kìíní- Àkólé iṣẹ́ – ÈDÈ- Ẹ̀yà ara ìfọ̀ ÀṢÀ – Ẹ̀kọ́ Ilé LIT – Lítíreṣọ̀
Èròngbà fún ẹ̀yà ara ìfọ̀
i. Fún ẹ̀yà ara ìfọ̀ ní oríkì
ii. Mẹ́nuba orísi ẹ̀yà ara ìfọ̀ tó wà
iii. Dárúkọ àwọn àfipè tí ó wà
Èròngbà fún àṣà
1. Sàlàyé ohun ti Èko ile jé.
2. So bí a se ñ ki ènìyàn ní àkókò àti ìgbà lólókan ò jokan.
3. Ménuba ipò tí okunrin àti obìrin máa n wà nígbà tí wón bá n kí àgbàlagbà.
Èròngbà fún lítíreṣọ̀
1. Ohun tí lítíreṣọ̀ jẹ́
2. Àwọn ẹ̀yà lítírẹṣọ̀
3. Dárúkọ àpẹẹrẹ Lítíréṣọ̀ àpilẹ̀kọ.
4. Sọ ohun tí Lítíréṣọ̀ alohùn jẹ́.